Iwin inu Okiti fi mi lakalaka, Mi ole gbagbe ojo ti mo pade Iwin Olori mejo, mo saisan fun opolopo ojo ki nto bori. Mogbo ilu ninu apata ninu aginju