Ogboju Ode|Mopa opolopo Iwin|Ni Ilu Offa, Awon Ole yin Ibon ni opolopo igba sugbon kowole simi lara
Baba mi ro mi lagabara ti mofi nko awon eye aje| Asiri agbara ti mofi npa ekun ati awon opolopo Eran abami yi wa pelu mi lako bi Ibon|.
wonyi ni awon Oro ti Baba Aluwo, Olori gbogbo awon Ode Ipinle Kwara, ti won tun je Baba Isale fun awon egbe Oduduwa Peoples Congress{OPC} so.